Ijoba by Adejoke Felicia Ft. Anointing Oluwaseun MP3 MUSIC
VIDEO
Ijoba LYRICS by Adejoke Felicia:
Chorus: Ijoba to so nu
Ijoba to sonu bawa wa
Ijoba to Kuna to wa so na afe o
Eleduwa oba ire abe o gba ko so
Solo1: on the increase of government oluwa.
Ninu itesi wa ju ijoba wa oluwa.
And for peace there will be no end
alafia koni do pin lailai o
Eleduwa oba ire abe o gbakoso
(Back to chorus Ijoba to sonu)
Aye ti fo ju tipe tipe
Idamu ba okan wa baba anbe o, are my aye to wa so na afe o
Eleduwa oba ire abe o gbakoso
(Back to chorus Ijoba to sonu)
.
Solo3: I will seek what was lost
Gbogbo owu rara to so nu ni ma gba pada
And bring back what was driven away
Eleduwa oba ire abe o gbakoso
(Back to chorus Ijoba to sonu bawa wa)
Aye ti shina oti pe
Idamu ba okan wa nbe o
Ani lo ite si wa ju oluwa to wa Sona
Idamu ba okan wa nbe o fun atunse
Ninu iporuru okan lan gbe ni gbogbo igba
Wa tun aye wa se
.Aye ti Sina oti pe
Idamu ba okan wa nbe o fun atunse afi oruko nla re be o
Dakun gbakoso
( Back to chorus Ijoba to sonu)
Ijoba Yi sisan ba wa da si
Oni segun nla o
Ani lo re fun iwo San nla
Do ki ta to mo ye wa wo wa San
Sanu… Wa.