African Music Lyrics EmmaOMG – Aigbagbo Bila

EmmaOMG – Aigbagbo Bila

Aigbagbo Bila by MP3 MUSIC VIDEO

Aigbagbo Bila LYRCIS by EmmaOMG:
Aigbagbo bila! Temi l’Oluwa
Oun o si dide fun igbala mi,
Ki n sa ma gbadura, Oun o se ‘ranwo:
‘Gba Krist’ wa lodo mi, ifoya ko si.

Bona mi ba su, Oun l’O sa n to mi,
Ki n sa gboran sa, Oun o si pese;
Biranlowo eda gbogbo ba saki,
Oro tenu Re so yo bori dandan

Leave a Reply