African Music Lyrics Olori Ogun – Abejoye Season 5 (Theme Song)

Olori Ogun – Abejoye Season 5 (Theme Song)

Olori Ogun Abejoye Season 5 (Theme Song) MP3 MUSIC VIDEO

Abejoye Season 5 Theme Song Olori Ogun Lyrics:
[Chorus]
Olori Ogun Lolugbala Mi
Ajagun segun lolugbeja mi
Ota to ba dena demi
Abogun lo ooo
Olori Ogun Lolugbeja Mi

Olori Ogun Lolugbala Mi
Ajagun segun lolugbeja mi
Ota to ba dena demi
Abogun lo ooo
Olori Ogun Lolugbeja Mi
Ota to ba dena demi
Abogun lo ooo
Olori Ogun Lolugbeja Mi

[Verse 1]
Egbe Ori Yin Soke
Eyin enu ona
Ki a si gbe yin soke
Eyin ilekun ayeraye
Oga ogo wo le wa
Oluwa to le to lagbara
Apata idigbolu
Oluwa to le ni ogun

Egbe Ori Yin Soke
Eyin enu ona
Ki a si gbe yin soke
Eyin ilekun ayeraye
Oga ogo wo le wa
Oluwa to le to lagbara
Apata idigbolu
Oluwa to le ni ogun

[Chorus]
Olori Ogun Lolugbala Mi
Ajagun segun lolugbeja mi
Ota to ba dena demi
Abogun lo ooo
Olori Ogun Lolugbeja Mi

[Verse 2]
Moti fi jesu se abo ati apata mi
Eni ba to mi ogun orun a run won
Ko s’ohun ija kan ti a se ti o le se
Oga ogojulo nbe leyin mi, ebila

Moti fi jesu se abo ati apata mi
Eni ba to mi ogun orun a run won
Ko s’ohun ija kan ti a se simo ti o le se
Oga ogojulo nbe leyin mi, ebila

[Chorus]
Olori Ogun Lolugbala Mi
Ajagun segun lolugbeja mi
Ota to ba dena demi
Abogun lo ooo
Olori Ogun Lolugbeja Mi

Olori Ogun Lolugbala Mi
Ajagun segun lolugbeja mi
Ota to ba dena demi
Abogun lo ooo
Olori Ogun Lolugbeja Mi

Leave a Reply