Home African Music Lyrics Tope Alabi – Halleluyah Ni Won Ma ko

Tope Alabi – Halleluyah Ni Won Ma ko

Halleluyah Ni Won Ma ko by MP3 MUSIC VIDEO

Halleluyah Ni Won Ma ko LYRCIS by Tope Alabi:
Hallelujah ni won ma ko
Hallelujah si wo olurun mi
Orin hallelujah ni woo bawon torun ko o

Oju orun fun dede
Awo San man ni Pele ni pele
Eru lo fi ko aye
Okun fun ajara
Eda o yanbo Awo
Ewo lo da Ara oto to
MO korin hallelujah si wo tan awon
Orun bo o

Again

Mimo Mimo ni won ke
Awon ti Eda orun angeli lowo lowoo
Won fi ojo jo fi ori bale o
Agba gba n ke Mimo
Si oludande aye gbogbo
Hallelujah si oni ite ogo aditu
Gbogboro owo to na aye ja lati inu orun wa Kikorin won o dake ri
Si olurun awon omo ogun

Leave a Reply