African Music Lyrics Tope Alabi – Iwo Lawa O Ma Bo

Tope Alabi – Iwo Lawa O Ma Bo


Iwo Lawa O Ma Bo by ft MP3 MUSIC VIDEO

Iwo Lawa O Ma Bo ft LYRCIS by Tope Alabi:
WA MA Gbemi MI ninu
WA MA Gbemi lokan
WA MA Tami googo bi eni mutin olowo nla
WA MA romi siwaju
Romi so eyin to move ndun ninu ree
Kabiesi olowo orimi oooo
Wa ma gbemi ninu se
Wa ma gbe wa likon
Iwo loni ayo to kun inu wa
Wa ma gbemi ninu
Wa ma gbe wa ninu wa ma ti wa googo
Kin se bi eni fe subu sugbon bi eni fe dunnu
Idunu wa lo po ninu ree
Ayo igbala ree kun inu waa
Kabiesi oo awa ma gbe oo ga
Iwo to poo ni ipa ati agbara

Leave a Reply